Ope o, Chelsea gba ife-eye FA Cup fungba keje, odun
Transcripción
Ope o, Chelsea gba ife-eye FA Cup fungba keje, odun
E ba wa dele E mo nipa wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Bi o ba fe ba wa sise Adiresi wa Ope o, Chelsea gba ife-eye FA Cup fungba keje, odun 1970 ni won koko gba a Awon Iroyin to se koko Ayinde Alaga Eyi ni bi won se bi i, bo I Rasidi Yekini se di agbaboolu nla ati dije kan bo se ku gan-an tawoôn ara ileô Britain ki i fi i sôere rara ni FA Cup ti woôn tun n pe ni Challenge Cup. Ninu asôekagba toôdun yii to waye nijeôrin, Satide, ni papa Egbe agbaboolu Chelsea lo n sajoyo pelu ife-eye FA todun yii isôere Wembley Tuntun ni Chelsea ati Liverpool ti koju ara woôn, awoôn oômoô Roberto Di Matteo si fiya jeô Liverpool, peôlu ami ayo meji si eôyoô kan, woôn si gba ife-eôyeô naa. Idije nla ni, ohun to si fa a ni pe FA Cup nidije akoôkoô ti woôn gbe kaleô fawoôn eôgbeô agbaboôoôlu lagbaaye. Sôaaju ife-eôyeô agbaye, iyeôn World Cup, ni woôn ti n gba a, ileô geôeôsi lo si ti koôkoô waye. Sôugboôn ni bayii, kari aye ni woôn ti teôwoô gba a. Lati ogunjoô, osôu keje, oôdun 1871, ti oôkunrin ti woôn n pe ni Charles Alcock atawoôn meôfa kan ti kora woôn joô ni yara iroyin ileesôeô iwe iroyin ileô Geôeôsi ti woôn n pe ni The Sportsman Newspaper, lati jiroro lori bi woôn yoo sôe da idije ti yoo pa gbogbo awoôn agbaboôoôlu ileô Geôeôsi poô ni English FA Cup ti beôreô si i larinrin, ina idije naa ko si jo ajoreôyin latigba naa. Charles Alcock yii, oômoô ileô Britain ni, elere idaraya ni, o si tun jeô oôkan ninu awoôn alakoOso ere boôoôlu alafeôseôgba ati boôoôlu alafigigba ti woôn n pe ni Cricket. Oun lo pepade eôleôni-meje sileesôeô iwe-iroyin naa. Awoôn to wa nibeô loôjoô naa ni> A. Stair to jeô akapo ajoô to n sôakoso ere boôoôlu nileô Geôeôsi, oôkunrin yii naa lo sôe reôfuri faina awoôn idije meôta ti woôn koôkoô gba nigba ti woôn beôreô, C.W. Stephenson, J.H. Gifford, M. P. Betts, D. Allport ati Oôgagun Francis Marindin to jeô oôkan ninu awoôn oômoô ogun ileô Britain. Awoôn eôgbeô agbaboôoôlu meôeôeôdogun ni woôn kopa ninu ti akoôkoô, Clapham Rovers wa ninu woôn. Oôjoô koôkanla, osôu koôkanla, oôdun 1871, ni woôn gba faina toôdun yeôn. Jarvis Kenrick to n gba boôoôlu fun Rovers lo si koôkoô ju boôoôlu sawoôn. Ayo meôta ni woôn ju sawoôn eôgbeô agbaboôoôlu ti woôn koju ninu ifigagbaga to beôreô idije oôhun. Wanderers ati Royal Engineers lo koju ara woôn ninu asôekagba idije akoôkoô naa. Kiki oômoôleewe lawoôn oômoô agbaboôoôlu Wanderers yii, sôugboôn awoôn oômoô ogun ileô Britain ni Royal Engineers. Ayo kan sodo ni Wanderers si fi na woôn, papa isôere Kennigton Oval, to wa ni London ni woôn ti gba asôekagba yii. Eôgbeôrun eeyan lo waa woran loôjoô yeôn, sôugboôn woôn ti yi orukoô papa isôere yii pada si Kia Oval bayii. Ni saa to teôle toôdun 1871 yeôn, Wanderers lo tun gba ife-eôyeô naa, Oxford University, iyeôn awoôn agbaboôoôlu ile-eôkoô giga Oxford ni woôn koju. Papa isôere Lillie Bridge ti ko gba ju eôgbeôrun meôta eeyan loô ni woôn ti gba asôekagba naa. Nigba to si maa di saa to teôle e, Oxford gba ifeeôyeô oôhun. Ife-eôyeô ti Chelsea gba nijeôrin yii nigba keje ti woôn yoo gba a. Oôdun 1970 ni woôn koôkoô gba a, loôjoô koôkanla, osôu keôrin, oôdun naa. Leeds United ni woôn figagbaga peôlu loôjoô naa ni papa isôere Ogun Agbekoya Baba mi ki i se oniwahala o, won puro mo on ni, - Gani omo Ejigbadero Kayeefi nla leyi o Gani si dunbu iya e bii eran leyin to fun un lounje Abiru ki leleyii Dayo yinbon pa egbon e n’Ibadan Alagba soosi lo n bayawo mi sun— Michael E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa Wembley Tuntun(Wembley New) ti woôn ti gba toôdun yii naa ni woôn ti gba a. Idi ti woôn sôe n pe papa isôere yii ni Wembley tuntun ni pe oôdun 2007 ni woôn tun un koô, nigba ti woôn wo ti teôleô ti woôn n pe ni Ojulowo Wembley (Wembley Original) loôdun 1923. Loôdun 1970 yii, oômi ni woôn ta peôlu Leeds United, ayo meji-meji ni woôn ju sawoôn ara woôn. Eôgbeôrun loôna oôgoôrun-un eeyan lo waa woran. Teôleô, ko too di pe woôn yi ofin to n sôakoso idije yii pada, bi ko ba seôni to bori ninu awoôn agbaboôoôlu meji to ba figagbaga leôyin aadoôrun-un isôeôju ti woôn fi gba boôoôlu, woôn maa tun un gba loôjoô mi-in ni. Sôugboôn nigba to ya, woôn yi i pada, aaye ati gba peônariti yoô, eyi ti ko si teôleô. Nnkan to sôeôleô loôdun 1970 laarin Chelsea ati Leeds niyeôn. Leôyin ti woôn gba saa kinni atikeji tan fun aadoôrun-un isôeôju, woôn fun woôn ni oôgboôn isôeôju si i, sibeô naa, ayo meji meji yeôn naa ni. Ohun ti ALAROYE gboô ni pe ayo oôjoô naa le debii pe koriko to wa lori papa isôere Wembley Tuntun naa moô pe nnkan n sôeôleô, ko sôe e ri nigba ti woôn maa fi gba a tan. Eyi lo mu ki ajoô FA gbe ifigagbaga eôleôeôkeji loô si Old Trafford, niluu London. Chelsea lo bori eôleôeôkeji yii sôa o, ko seôni to gbagboô pe woôn le na Leeds, bo sôe sôeôleô loôdun yii naa lo sôeôleô nigba yeôn, abi ta lo le soô ni nnkan bii oôseô meôta seôyin pe Chelsea le gba ife-eôyeô kan loôdun yii peôlu bi ina woôn sôe n jo ajoreôyin latigba ti saa oôdun yii ti beôreô. Sôugboôn woôn joô gbogbo eeyan loju, awoôn alatileôyin woôn ti woôn ti loô teôleô si beôreô si i pada. Leôyin ogun oôdun ti Chelsea ti koôkoô gba a, oôdun 1997 loôwoô woôn tun too teô eô. Loôdun naa, Middlesbrough ni woôn fiya jeô. Leôyin eô ni woôn tun gba a loôdun 2000, 2007, 2009, 2010 ati 2012 yii. Igba moôkanla ni woôn ti woô faina idije naa, eôeômeôrin pere ni woôn ja boô. Manchester United lo sôi fitan baleô ju ninu awoôn agbaboôoôlu ileô England ninu idije FA . Eôeômejidinlogun lawoôn nikan ti woô faina< woôn gba ife-eôyeô nigba moôkanla, woôn si ja boô nipele faina nigba meje. Arsenal lo teôle woôn< awon wo faina nigba meôtadinlogun< woôn gba ife-eôyeô nigba meôwaa, woôn ja boô nigba meje. Tottenham Hotspur lo sôepo keôta< awoôn gba ifeeôyeô nigba meôjoô, woôn si ja boô leôeôkan sôosôo. Ipo karun-un ni Chelsea wa ninu awoôn to fitan baleô, Liverpool ti woôn koju nijeôrin lo wa nipo keôrin. Sôugboôn ayo oôjoô naa ko roôrun fun Chelsea o, o le ku ni, oôpeôloôpeô Drogba, oômoô ileô Afrika to sôe beôbeô fun Kiloôoôbu naa, oun gan-an lo papa kansôo moô posi ti woôn fi sin Liverpool. Ayo meji ni Chelsea ju sawoôn Liverpool, sôugboôn awoôn Reds, geôgeô bi woôn ti n pe woôn da eôyoô kan pada. Oôdoômoôkunrin to n yoô laalaalaa loôwoô fun Chelsea, Ramires, lo koôkoô ju boôoôlu sawoôn, eôyoô kan yeôn naa ni woôn si di mu ti woôn fi woô ipele keji. Ipele keji ni Drogba ti ju ekeji si i, ko too di pe awoôn oômoô Liverpool da okan pada