Helenio Herrera, okunrin to se gudugudu meje, yaaya
Transcripción
Helenio Herrera, okunrin to se gudugudu meje, yaaya
E ba wa dele E mo nipa wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Bi o ba fe ba wa sise Helenio Herrera, okunrin to se gudugudu meje, yaaya mefa fun Inter Milan, ife-eye meje loun nikan gba fun won Adiresi wa Awon Iroyin to se koko Igbejo Daniel: Adajo fee ju Daniel sewon, Ayinde Alaga looya e lo ko o yo E ôyin ololufeô wa, eô ku deede iwoyi o, eô si ku oôjoô meôta kan, gbogbo nnkan to n pa wa leôrin-in ko ma ni i pa wa leôkun loôla Alawurabi, aridunnu wa ko ni i di ibanujeô. Loôseô to koôja la fi itan baleô lori bi woôn sôe da eôgbeô agbaboôoôlu Inter Millan sileô, a jeô ko di mimoô pe ija kan to beô sileô laarin awoôn ololufeô AC Millan lo sôokunfa eôgbeô agbaboôoôlu Inter loôjoô keôsanan, osôu keôta, oôdun 1908, iyeôn leôyin oôdun meôsan-an teôgbeô naa ti Hellenio Herrera, wa nigboro. A jeô ko di mimoô pe orogun atayebaye lawoôn eôgbeô mejeeji, boôoôlu to ba si pa awoôn mejeeji poô maa n dun koôja bo sôe yeô nitori ero iworan maa n poô nibeô. Derby Della Madonnia ni woôn maa n pe iru ere boôoôlu beôeô. Eôyin temi, bi toôseô to koôja sôe loô niyeôn ni soki, eô jeô ki a teô peôpeô toôseô yii naa kaleô geôgeô bi a sôe soô loôseô to koôja pe bi oômoôde ko ba itan, aa ba aroôba ti i sôe baba itan. A feôeô tan asôeyoôri Inter Milan yeôbeôyeôbeô, a feôeô wo bi woôn sôe sôe e gan-an. Oôkan ninu awoôn agbaboôoôlu Inter Millan to fitan baleô geôgeô bii agbaboôoôlu to gba boôoôlu to poô juloô woôle, paapaa ninu idije Liigi Seria A orileô-ede Italy, Guseppe Meazza, orukoô reô ni woôn maa fi n pe papa isôere ti woôn soô di San Siro bayii teôleô. Ojilenigba ati marun-un (245) boôoôlu ni Guseppe Meazza gba sawoôn ninu ojileloôoôoôdunrun ati meôjoô (348) ere boôoôlu to ti kopa. Lara awoôn akoôni-moô-oôn-gba ti woôn ti sôisôeô ni Inter Milan ni gbara ti woôn beôreô ni nnkan bii oôgoôrun-un oôdun o le dieô ni Virgilio Fossati, oômoô orileô-ede Italy nibeô loun naa. Laarin oôdun 1905 si 1915 lo fi sôisôeô, leôyin eô ni Nino Resegoth ati Francesco Mauro tawoôn naa jeô oômoô Italy naa sôisôeô nibeô laarin oôdun 1919 si 1920. O·moô orileô-ede England ni Bob Spotishwood ni tieô, 1922 si 1924 loun sôe koosôi nibeô. Lara awoôn ti a tun le toôka si ni Arapad Weisz, Jozsef Viola, Istvan Toth, Gyrla Feidman, Albino Carraro ati beôeô beôeô loô, gbogbo woôn naa ni woôn sôisôeô ni Inter, sôugboôn bi woôn sôe poô to yii, awoôn ti woôn koôkoô sôisôeô akoôni-moô-oôn-gba ni gbara ti woôn da eôgbeô oôhun sileô ko lasôeyoôri ti a le toôka si ti a ba ti yoôwoô Virgilio Fassati to jeô oôkan lara awoôn koosôi to sôisôeô laarin oôdun 1909 si 1915 to gba ade Liigi leôeôkan sôosôo. Nino Resegotti naa gbade Liigi leôeôkan sôosôo. Beôeô naa ni Arpad Welsz ati Armando Gastellazzi. Austria Tony Cargnelli naa sôisôeô ni Inter Milan laarin oôdun 1936 si 1938. Leyin awuyewuye odun merin Amosun gbe opa ase fun Olu Ilaro tuntun Eeyan merindinlaaadota lo jona ku nipinle Oyo Fasola seto ayewo ilera fawon ara Eko O ma se o! Femi, osise banki gan mona pelu awon meta mi-in n’Ilesa Wahala niluu Igbogbo! Awon janduku fipa ba awon omobinrin ilu sun, won tun na won jatijati E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa Ni ti Tony, Ife-eôyeô meji oôtoôoôtoô lo gba ni saa tireô, o gbade Liigi Seria A, o tun gba ife-eôyeô Coppa Italia, igba koôoôkan lo gba awoôn ife-eôyeô mejeeji laarin akoko to fi tukoô eôgbeô naa. Leôyin tireô ni Alfredo Foni to sôisôeô loôdun 1952 si 1955, oun naa gbade Liigi Seria A nigba meji oôtoôoôtoô. Laarin awoôn koosôi to sôisôeô leôgbeô yii lati oôdun 1908 ti woôn da a sileô titi di 1960, bi woôn ti sôe poô to yii, ko seônikan ninu woôn to firu itan ti akoônimoô-oôn-gba woôn yii fi leleô. Argentina Helenio Herrera lorukoô eô. Oômoô orileô-ede Argentina ni, 1960 si 1968 lo fi sôisôeô poô peôlu woôn, di bi a sôe n koô itan yii, boya ni koosôi kan wa to peô to bayii ni Inter Millan, saa igbaboôoôlu meôsan-an oôtoôoôtoô lo lo geôgeô bii akoôni-moô-oôngba eôgbeô yii; beôreô lati saa oôdun 1960 si 1961, titi di 1967 si 1968. Ni gbogbo asiko yii, ere boôoôlu oôtaleloôoôoôdunrun ati meôfa (366) lo ko eôgbeô naa sodi gba geôgeô bii koosôi woôn. Ninu gbogbo ere boôoôlu oôhun, igba ati marun-un (205) lo bori ninu woôn, o ta oômi ninu meôtalelaaadoôrun-un (93), o s i padanu ninu idije mejidinlaaadoôrin (68). Ni oôdun meôsan-an to lo geôgeô bii koosôi woôn yii, ife-eôyeô meje oôtoôoôtoô lo gba, o gbade Liigi oôwoô kin-in-ni orileô-ede Italy ti a moô si Seria A nigba meôta oôtoôoôtoô, igba meji leralera lo gba ife-eôyeô eôgbeô agbaboôoôlu to dangajia juloô nileô alawoô funfun, iyeôn European Cup ti woôn n pe ni Champions League bayii, iyeôn loôdun 1964 ati 1965, bakan naa lo gba ifeeôyeô Inter Continental nigba meji. Eôyin ololufeô abala ere idaraya, paapaa eôyin ti eô n foôkan ba itan wa boô, eô o ri i pe nnkan ki seôseô rago ni asôeyoôri oôkunrin oômoô bibi ile ô Argentina to waa sôisôeô ni Inter yii. A-ri-sôe-la-ri-ka, a-ri-ka ni baba iregun, Helenio Herrera sôe gudugudu meje oun yaaya meôfa, o gbounjeô feôgbeô, o tun duro gba awo reô boô ni Millan. Eôyin onkawe wa, ibi yii ni a feôeô dawoô duro si na lori itan yii, to ba di loôseô to n boô, a o tun maa teô siwaju. Titi oôseô to n boô, a o ni i sare wa ara wa funbi, beôeô la o ni i feônikeôni sôawati. Ire o.
Documentos relacionados
O ma se o: Bi aisan ito-suga se pa Iyalode Adunni Bankole
tun moô si Iya rere. Bawoôn osôere sôe n banujeô lori isôeôleô oôhun lawoôn soôroôsoôroô ori redio ati teôlifisôan n soô pe iku to pa Iyalode ilu Gbagura yii ko sôe ohun rere. Lara awoôn agba soôro...
Más detallesOpe o, Chelsea gba ife-eye FA Cup fungba keje, odun
waye. Sôugboôn ni bayii, kari aye ni woôn ti teôwoô gba a. Lati ogunjoô, osôu keje, oôdun 1871, ti oôkunrin ti woôn n pe ni Charles Alcock atawoôn meôfa kan ti kora woôn joô ni yara iroyin ileesôeô...
Más detalles